Plánẹ́tì
From Wikipedia
Plánẹ́tì gege bi Agbajo-egbe Agbaye aseto Irawo (IAU) se se'tumo re je ohun oke-orun ti o n yi irawo ka tabi aloku orun ti iwuwosi re je ki o ri roboto, ti ko tobi pupo lati gba yiyo igbonainuikun (thermonuclear fusion) laaye ninu re, ti o si ti gba awon orisirisi idena kuro lona ti o n gba koja.
[edit] Awon Planeti ti o wa ninu Ètò Òòrùn
Gege bi (IAU) se so, planeti mejo ni won wa ninu ètò òòrùn. Awon niwonyi bi won se njinna si Òòrùn:
- (
) Mekiuri - (
) Fenosi - (
) Ilẹ̀-ayé - (
) Maasi - (
) Jupita - (
) Satonu - (
) Uranosi - (
) Neptunu

